Tag Archives: YORUBA RCCG SUNDAY SCHOOL FOR 5 FEBRUARY 2023

YORUBA RCCG SUNDAY SCHOOL TEACHER’S MANUAL ỌJỌ́ KARÙN ÚN, OSU KEJI, ỌDÚN 2023.

IWE ILE EKO OJO ISINMI TI OLUKO TI ODUN 2023

Ẹ̀KỌ́ KẸTÀLÉLÓGÚNAKORI: ÈSO TI Ẹ̀MÍ MÍMỌ́ (APÁ KÍNNÍ) ÀDÚRÀ ÌBẸ̀RẸ̀: Baba, jọ̀wọ́ rànmílọ́wọ́ nínú ìlàkàkà mi láti kọ́ bí a ṣe ń gbé ìgbé ayé ìwà-bí-Ọlọ́run ní orúkọ Jesù. BÍBÉLÌ KÍKÀ: Galatia 5:22-23. 22. Ṣugbọn eso ti Ẹmí ni ifẹ, ayọ̀, alafia, ipamọra, ìwa pẹlẹ, iṣore, igbagbọ́, 23. Ìwa tutù, …

Read More »