Ẹ̀KỌ́ KẸTÀLÉLÓGÚNAKORI: ÈSO TI Ẹ̀MÍ MÍMỌ́ (APÁ KÍNNÍ) ÀDÚRÀ ÌBẸ̀RẸ̀: Baba, jọ̀wọ́ rànmílọ́wọ́ nínú ìlàkàkà mi láti kọ́ bí a ṣe ń gbé ìgbé ayé ìwà-bí-Ọlọ́run ní orúkọ Jesù. BÍBÉLÌ KÍKÀ: Galatia 5:22-23. 22. Ṣugbọn eso ti Ẹmí ni ifẹ, ayọ̀, alafia, ipamọra, ìwa pẹlẹ, iṣore, igbagbọ́, 23. Ìwa tutù, …
Read More »