Devotional 2023

YORUBA RCCG SUNDAY SCHOOL TEACHER’S MANUAL Ẹ̀KỌ́ KẸẸ̀DỌ́GBỌ̀N: ỌJỌ́ KOKÀNDÍNLÓGÚN, OSU KEJI, ỌDÚN 2023

IWE ILE EKO OJO ISINMI TI OLUKO TI ODUN 2023

YORUBA RCCG SUNDAY SCHOOL TEACHER’S MANUAL Ẹ̀KỌ́ KẸẸ̀DỌ́GBỌ̀N: ỌJỌ́ KOKÀNDÍNLÓGÚN, OSU KEJI, ỌDÚN 2023 – AKORI: AGBÁRA YÍYÀN À̀DÚRÀ ÌBẸ̀RẸ̀: Baba, kọ́mi láti lóye nípa agbára yíyàn kí n má bàá kọ lọ́nà ipá. ÌMỌ̀ ÀTẸ̀HÌNWÁ: Kí olùkọ́ gba akẹ́kọ̀ọ́ kan láyè láti ṣe àtúnyẹ̀wò ẹ̀kọ́ ti ọ̀sẹ̀ tó kọjá. …

Read More »